Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria, ede, asa, ati litireso n ko ipa pataki ninu itan won lati igba ti won ti da ekun ariwa ati guusu papo ni odun 1914. ninu aoileko yli, a lo tiori imo ajemotan-tuntun ati tiori imo asa lati sayewo ipa...
Saved in:
| Main Author: | |
|---|---|
| Format: | Artigo |
| Language: | Inglês |
| Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://journals.flvc.org/ysr/article/view/130151 |
| Tags: |
No Tags, Be the first to tag this record!
|
